Skip to content
The Believer's Library

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible 2017

Psalms 150 OYCB

Side by side with the Father's Heart Bible™

1Ẹ fi ìyìn fún Olúwa.Ẹ fi ìyìn fún Ọlọ́run ní ibi mímọ́ rẹ̀,ẹ yìn ín nínú agbára ọ̀run rẹ̀.

2Ẹ yìn ín fún iṣẹ́ agbára rẹ̀.Ẹ yìn ín fún títóbi rẹ̀ tí ó tayọ̀.

3Ẹ fi ohùn ìpè yìn ín.Ẹ fi ohun èlò orin yìn ín.

4Ẹ fi ohun èlò orin àti ijó yìn ínfi ohun èlò orin olókùn àti ìpè yìn ín,

5Ẹ yìn ín pẹ̀lú aro olóhùn òkè,ẹ yìn ín lára aro olóhùn gooro.

6Jẹ́ kí gbogbo ohun tí ó ní ẹ̀mí yin Olúwa.Ẹ fi ìyìn fún Olúwa.

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 Biblica, Inc. Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. ‪“Biblica” ni àmì ìdámọ̀ tí Biblica, Inc. fi sílẹ̀ ní United States Patent àti ní ilé iṣẹ́ tí wọ́n ti ń fúnni ní àmì ìdámọ̀. Gba àṣẹ kí o tó lòó. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission.
Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible 2017 · Creative Commons - Attribution-ShareAlike [CC BY-SA]