Skip to content
The Believer's Library

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible 2017

Numbers 17 OYCB

Show OYCB only
Verse × ×
1 Then our Father spoke to Moses, saying: Olúwa sì sọ fún Mose pé,
2 "Tell Eleazar son of Aaron the priest to take the censers from the burning coals and scatter the fire far off—they are holy. “Sọ fún àwọn ọmọ Israẹli kí o sì gba ọ̀pá méjìlá lọ́wọ́ wọn, ọ̀kọ̀ọ̀kan lọ́wọ́ olórí ìdílé ẹ̀yà ìran wọn, kọ orúkọ ènìyàn kọ̀ọ̀kan sí ara ọ̀pá rẹ̀.
3 The censers of these men who sinned at the cost of their lives. Hammer them into plates to cover the altar—since they were presented before me and became holy—as a sign to the sons of Israel." Lórí ọ̀pá Lefi kọ orúkọ Aaroni, nítorí ọ̀pá kọ̀ọ̀kan gbọdọ̀ wà fún olórí ìdílé kọ̀ọ̀kan tí yóò jẹ́ orí fún ẹ̀yà ìran kọ̀ọ̀kan.
4 Eleazar the priest took the bronze censers that those who were burned had offered, then hammered them into a covering for the altar. Kó wọn sí àgọ́ ìpàdé níwájú ẹ̀rí níbi tí èmi ti ń pàdé yín.
5 A reminder to Israel's sons that no outsider—not of Aaron's offspring—may approach to burn incense before our Father, so he wouldn't become like Korah and his company, as our Father told Aaron through Moses. Ọ̀pá tí ó bá yí jẹ́ ti ẹni tí èmi bá yàn yóò rúwé, èmi yóò sì dá kíkùn gbogbo ìgbà àwọn ọmọ Israẹli sí yín dúró.”
6 The next day the whole congregation of Israel's sons grumbled against Moses and Aaron: "You have killed the people of our Father." Nígbà náà Mose bá àwọn ọmọ Israẹli sọ̀rọ̀, àwọn olórí wọn sì fún un ní ọ̀pá méjìlá, ọ̀pá kan fún olórí kọ̀ọ̀kan ẹ̀yà ìran wọn, ọ̀pá Aaroni sì wà lára àwọn ọ̀pá náà.
7 When the assembly gathered against Moses and Aaron, they turned toward the tent of meeting, and the cloud covered the tent, and the glory of our Father appeared. Mose sì fi ọ̀pá wọ̀nyí lélẹ̀ níwájú Olúwa nínú àgọ́ ẹ̀rí.
8 Then Moses and Aaron came to the front of the tent of meeting. Ó sì ṣe ní ọjọ́ kejì Mose wọ inú àgọ́ ẹ̀rí lọ, ó sì rí ọ̀pá Aaroni, tí ó dúró fún ẹ̀yà Lefi, kì í ṣe wí pé ó hù nìkan, ṣùgbọ́n ó rúwé, ó yọ ìtànná, ó sì so èso almondi.
9 And our Father spoke to Moses, saying: Nígbà náà ni Mose kó gbogbo àwọn ọ̀pá jáde láti iwájú Olúwa wá fún àwọn ọmọ Israẹli. Wọ́n wò wọ́n, ẹnìkọ̀ọ̀kan sì mú ọ̀pá tirẹ̀.
10 "Move away from this congregation so I can destroy them instantly." And they fell on their faces. Olúwa sọ fún Mose pé, “Mú ọ̀pá Aaroni padà wá síwájú ẹ̀rí, láti fi pamọ́ gẹ́gẹ́ bí àmì fún àwọn ọlọ̀tẹ̀. Èyí ó sì mú òpin bá kíkùn sínú wọn sí mi, kí wọn kí ó má ba à kú.”
11 Moses told Aaron, "Take the censer, put fire on it from the altar, add incense, and rush it to the community to atone for them, for wrath has gone out from before our Father; the plague has begun." Mose sì ṣe gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti páláṣẹ fún un.
12 Aaron took it as Moses said, ran into the midst of the assembly—the plague had already begun among the people—burned the incense, and made atonement for the people. Àwọn ọmọ Israẹli sọ fún Mose pé, “Àwa yóò kú! A ti sọnù, gbogbo wa ti sọnù!
13 And he stood between the dead and the living, and the plague was stopped. Ẹnikẹ́ni tí ó bá súnmọ́ tabanaku Olúwa yóò kú. Ṣé gbogbo wa ni yóò kú?”
14 Those who died in the plague numbered 14,700, besides those who died over Korah. Not in this edition
15 Aaron returned to Moses at the entrance of the tent of meeting, for the plague had been stopped. Not in this edition
16 Then our Father spoke to Moses, saying: Not in this edition
17 "Speak to the sons of Israel and take from them a staff for each ancestral house—twelve staffs from all their leaders by ancestral house. Write each man's name on his staff. Not in this edition
18 Write Aaron's name on Levi's staff, for one staff per head of each ancestral house. Not in this edition
19 Place them in the tent of meeting before the testimony, where I meet with you. Not in this edition
20 The staff of the man I choose will sprout, and so I'll quiet before me the grumbles of Israel's sons who grumble against you." Not in this edition
21 Moses spoke to the Israelites, and each leader gave him a staff—one per leader per ancestral house, twelve staffs—with Aaron's staff among them. Not in this edition
22 And Moses placed the staffs before our Father in the tent of the testimony. Not in this edition
23 The next day Moses entered the tent of testimony and found Aaron's staff, for the house of Levi, had sprouted—budded, blossomed, and produced ripe almonds. Not in this edition
24 Moses brought all the staffs out from before our Father to all the sons of Israel; they looked, and each man took his own staff. Not in this edition
25 And our Father told Moses, "Put Aaron's staff back before the testimony, kept as a sign for the rebels, to end their grumbling against me, so they won't die." Not in this edition
26 And Moses did so; just as our Father had commanded him, so he did. Not in this edition
27 The sons of Israel said to Moses, "Look, we are dying, we are lost, all lost! Not in this edition
28 Anyone who comes near, who comes near our Father's tabernacle, dies. Will we all perish?" Not in this edition
FHB

Scripture from Father’s Heart Bible™. © 2026 Spirit Media Publishing, the imprint of Spirit Media Inc. All rights reserved. In Divine Voice™ Color, the words spoken by our Father show in blue, the words of the Son in red, and the words of the Spirit in purple.

OYCB

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 Biblica, Inc. Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. ‪“Biblica” ni àmì ìdámọ̀ tí Biblica, Inc. fi sílẹ̀ ní United States Patent àti ní ilé iṣẹ́ tí wọ́n ti ń fúnni ní àmì ìdámọ̀. Gba àṣẹ kí o tó lòó. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission.
Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible 2017 · Creative Commons - Attribution-ShareAlike [CC BY-SA]