Skip to content
The Believer's Library

Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible 2017

1 Chronicles 8 OYCB

Show OYCB only
Verse × ×
1 Benjamin fathered Bela his firstborn, Ashbel the second, Aharah the third, Benjamini jẹ́ baba: Bela àkọ́bí rẹ̀, Aṣbeli ọmọkùnrin ni ẹ̀ẹ̀kejì, Ahara ẹ̀ẹ̀kẹ́ta,
2 Nohah the fourth, and Rapha the fifth. Noha ẹ̀ẹ̀kẹrin àti Rafa ẹ̀karùnún.
3 Bela had sons: Addar, Gera, Abihud, Àwọn ọmọ Bela ni, Adari, Gera, Abihudi,
4 Abishua, Naaman, Ahoah, Abiṣua, Naamani, Ahoa,
5 Gera, Shephuphan, and Huram. Gera, Ṣefufani àti Huramu.
6 These were Ehud's sons—clan heads over Geba's residents, exiled to Manahath: Wọ̀nyí ni àwọn ìran ọmọ Ehudu, tí wọ́n jẹ́ olórí àwọn ìdílé tí ó ń gbé ní Geba tí a sì lé kúrò lọ sí Manahati:
7 Naaman, Ahijah, and Gera—Gera exiled them—and fathered Uzza and Ahihud. Naamani Ahijah àti Gera, tí ó lé wọn kúrò ní ìlú, àti tí ó sì jẹ́ baba Ussa àti Ahihudu.
8 Shaharaim fathered children in Moab's territory after sending away his wives Hushim and Baara. A bí àwọn ọmọkùnrin fún Ṣaharaimu ní Moabu lẹ́yìn tí ó ti kọ àwọn ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀, Huṣimu àti Baara.
9 By his wife Hodesh he fathered Jobab, Zibia, Mesha, Malcam, Nípasẹ̀ ìyàwó rẹ̀ Hodeṣi ó ní Jobabu Sibia, Meṣa, Malkamu,
10 Jeuz, Sachia, and Mirmah. These were his sons, heads of families. Jeusi, Sakia àti Mirma. Wọ̀nyí ni àwọn ọmọkùnrin rẹ̀, olórí àwọn ìdílé.
11 By Hushim he fathered Abitub and Elpaal. Nípasẹ̀ Huṣimu ó ní Abitubu àti Elipali.
12 The sons of Elpaal: Eber, Misham, and Shemed, who built Ono and Lod with its surrounding towns, Àwọn ọmọ Elipali: Eberi, Miṣamu, Ṣemedu (ẹni tí ó kọ́ Ono àti Lodi pẹ̀lú àwọn ìletò àyíká rẹ̀.)
13 Beriah and Shema were family heads of Aijalon's residents; they drove out Gath's residents. Pẹ̀lú Beriah àti Ṣema, tí wọ́n jẹ́ olórí àwọn ìdílé ti àwọn tí ó ń gbé ní Aijaloni àti àwọn tí ó lé àwọn olùgbé Gati kúrò.
14 Ahio, Shashak, Jeremoth, Ahio, Ṣasaki, Jeremoti,
15 Zebadiah, Arad, Eder, Sebadiah, Aradi, Ederi
16 Michael, Ishpah, and Joha were the sons of Beriah. Mikaeli, Iṣifa àti Joha jẹ́ àwọn ọmọ Beriah.
17 Zebadiah, Meshullam, Hizki, Heber, Sebadiah, Meṣullamu, Hiski, Heberi
18 Ishmerai, Izliah, and Jobab were the sons of Elpaal. Iṣimerai, Isiliahi àti Jobabu jẹ́ àwọn ọmọ Elipali.
19 Jakim, Zichri, Zabdi, Jakimu, Sikri, Sabdi,
20 Elienai, Zillethai, Eliel, Elienai, Siletai, Elieli,
21 Adaiah, Beraiah, and Shimrath were the sons of Shimei. Adaiah, Beraiah àti Ṣimrati jẹ́ àwọn ọmọ, Ṣimei.
22 Ishpan, Eber, Eliel, Iṣipani Eberi, Elieli,
23 Abdon, Zichri, Hanan, Abdoni, Sikri, Hanani,
24 Hananiah, Elam, Anthothijah, Hananiah, Elamu, Anitotijah,
25 Iphdeiah, and Penuel were the sons of Shashak. Ifediah àti Penueli jẹ́ àwọn ọmọ Ṣasaki.
26 Shamsherai, Shehariah, Athaliah, Ṣamṣerai, Ṣeharaiah, Ataliah
27 Jaareshiah, Elijah, and Zichri were the sons of Jeroham. Jareṣiah, Elijah àti Sikri jẹ́ àwọn ọmọ Jerohamu.
28 These were family heads and chiefs, recorded in their genealogies; they lived in Jerusalem. Gbogbo àwọn wọ̀nyí jẹ́ olórí àwọn ìdílé, olóyè gẹ́gẹ́ bí a ti kọ ọ́ lẹ́sẹẹsẹ nínú ìtàn ìran wọn, wọ́n sì ń gbé ní Jerusalẹmu.
29 In Gibeon lived the father of Gibeon, whose wife was named Maacah, Jeieli, baba Gibeoni ń gbé ní Gibeoni. Ìyàwó o rẹ̀ a má jẹ́ Maaka,
30 and his firstborn son was Abdon, then Zur, Kish, Baal, Nadab, àkọ́bí rẹ̀ a sì máa jẹ́ Abdoni wọ̀nyí sì ń tẹ̀lé Suri, Kiṣi, Baali, Neri, Nadabu,
31 Gedor, Ahio, and Zecher. Gedori Ahio, Sekeri
32 Mikloth fathered Shimeah. These too lived alongside their relatives in Jerusalem. pẹ̀lú Mikiloti, tí ó jẹ́ baba Ṣimea. Wọ́n ń gbé ní ẹ̀bá ìbátan wọn ní Jerusalẹmu.
33 Ner fathered Kish, Kish fathered Saul, and Saul fathered Jonathan, Malchi-shua, Abinadab, and Eshbaal. Neri jẹ́ baba Kiṣi, Kiṣi baba Saulu àti Saulu baba Jonatani, Malikiṣua, Abinadabu àti Eṣi-Baali.
34 The son of Jonathan was Merib-baal, and Merib-baal fathered Micah. Ọmọ Jonatani: Meribu-Baali tí ó jẹ́ baba Mika.
35 The sons of Micah: Pithon, Melech, Tarea, and Ahaz. Àwọn ọmọ Mika: Pitoni, Meleki, Tarea, àti Ahasi.
36 Ahaz fathered Jehoaddah, Jehoaddah fathered Alemeth, Azmaveth, and Zimri, and Zimri fathered Moza. Ahasi jẹ́ baba a Jeheada, Jeheada jẹ́ baba a Alemeti, Asmafeti àti Simri, Simri sì jẹ́ baba Mosa.
37 Moza fathered Binea; Raphah was his son, Eleasah his son, Azel his son. Mosa jẹ́ baba Binea; Rafa sì jẹ́ ọmọ rẹ̀, Eleasa ọmọ rẹ̀ àti Aseli ọmọ rẹ̀.
38 Azel's six sons: Azrikam, Bocheru, Ishmael, Sheariah, Obadiah, Hanan—all sons of Azel. Aseli ní ọmọ mẹ́fà pẹ̀lú wọ̀nyí ni orúkọ wọn: Asrikamu, Bokeru, Iṣmaeli, Ṣeariah, Obadiah àti Hanani. Gbogbo wọ̀nyí ni ọmọ Aseli.
39 The sons of Eshek his brother: Ulam his firstborn, Jeush the second, and Eliphelet the third. Àwọn ọmọ arákùnrin rẹ̀ Eseki: Ulamu àkọ́bí rẹ̀, Jeuṣi ọmọkùnrin ẹ̀ẹ̀kejì àti Elifeleti ẹ̀ẹ̀kẹ́ta.
40 Ulam's sons were mighty warriors, skilled archers, with many sons and grandsons—150 in all. All these were sons of Benjamin. Àwọn ọmọ Ulamu jẹ́ ògboyà jagunjagun tí ó lè gbá orin mú. Wọ́n ní ọ̀pọ̀ ọmọkùnrin àti ọmọ ọmọkùnrin áàdọ́jọ ní gbogbo rẹ̀. Gbogbo wọ̀nyí ni àwọn ìdílé ìran ọmọ Benjamini.
FHB

Scripture from Father’s Heart Bible™. © 2026 Spirit Media Publishing, the imprint of Spirit Media Inc. All rights reserved. In Divine Voice™ Color, the words spoken by our Father show in blue, the words of the Son in red, and the words of the Spirit in purple.

OYCB

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 Biblica, Inc. Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. ‪“Biblica” ni àmì ìdámọ̀ tí Biblica, Inc. fi sílẹ̀ ní United States Patent àti ní ilé iṣẹ́ tí wọ́n ti ń fúnni ní àmì ìdámọ̀. Gba àṣẹ kí o tó lòó. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission.
Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible 2017 · Creative Commons - Attribution-ShareAlike [CC BY-SA]